Ojumo ti mo Ojumo ti mo mi, nile yi Ojumo ti mo, mo rire o
Ojumo ti mo Ojumo ti mo mi, nile yi o Ojumo ti mo, mo rire o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
Ojumo ti mo Ojumo ti mo mi, nile yi o Ojumo ti mo, mo rire o
Ojumo ti mo Ojumo ti mo mi, nile yi o Ojumo ti mo, mo rire o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke [Ha] Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o [Ha, eei k ngbo se] Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o